placeholder image to represent content

1ST YORUBA TEST YEAR 6

Quiz by Akin Ajayi

Our brand new solo games combine with your quiz, on the same screen

Correct quiz answers unlock more play!

New Quizalize solo game modes
25 questions
Show answers
  • Q1
    1. Alifabeeti Ede Yoruba ni akojopo ________ ( __________ make up the Yoruba Alphabets)
    iro
    faweli
    konsonanti
    leta
    45s
  • Q2
    2. Alifabeeti _________________ lo wa ninu Ede Yoruba. ( There ____________ alphabets in Yoruba language)
    maundinlogun
    marundinlogbon
    metadinlogbon
    metadinlogun
    45s
  • Q3
    3. Ona ____________ otooto ni a pin alifabeeti ede Yoruba si. ( The Yoruba alphabet is divided into __________ parts)
    merin
    marun-un
    meta
    meji
    45s
  • Q4
    4. Apopo Iro faweli Ede Yoruba je _________ ( The total number of vowels in Yoruba language is _____________)
    marun-un
    meji
    mejila
    meje
    45s
  • Q5
    5. Faweli aranmupe Ede Yoruba je ____________ (There are ___________ nasalized vowels in Yoruba language)
    mewaa
    meje
    mejo
    marun-un
    45s
  • Q6
    6. Iye Faweli airanmupe Ede Yoruba ni __________ ( There are _________ oral vowels in Yoruba language)
    mefa
    meji
    meje
    marun
    45s
  • Q7
    7. Iru konsonanti wo ni iro "m" ati "n" je? ( What type of consonants are letters m and n in Yoruba language?)
    afojupe
    afenupe
    aranmupe
    airanmupe
    45s
  • Q8
    8. Leta "b" ati "d" je apeere konsonanti ________ ( The letters b and d are examples of ______________ consonants)
    afojupe
    airanmupe
    aranmupe
    afenupe
    45s
  • Q9
    9. Apapo konsonanti Ede Yoruba je ____________ ( The total number of consonants in Yoruba language is _______________)
    mejidinlogbon
    mejidinlogbon
    mejidinlogun
    marundinlogun
    45s
  • Q10
    10. Konsonanti aranmupe Ede Yoruba je ___________ ( How many are the oral consonants in Yoruba ?)
    mookanla
    metadinlogun
    merindinlogun
    merindinlogun
    45s
  • Q11
    11. _____________ ni baba Oduduwa. ( _____________ was Oduduwa's father)
    Buraimo
    Lamurudu
    Agbonmiregun
    Asara
    30s
  • Q12
    12. Ilu ________________ ni awon mejeeji oke yii n gbe. (The above mentioned people were leaving in ____________)
    Medina
    Ile-Ife
    Oyo
    Meka
    30s
  • Q13
    13. Oruko omo Asara ni ilu Meka ni ____________ ( What was Asara's son name who lived in Mecca?)
    Onisabe
    Oduduwa
    Lamurudu
    Buraimo
    30s
  • Q14
    14. Ija ____________ lo be sile ti awon elesin ibile se sa kuro ni ilu Meka. ( The traditional worshipers left Mecca because of _______________ war)
    ominira
    esin
    alaafia
    ade
    45s
  • Q15
    15. Ojo melo ni awon ni Oduduwa ati awon alatele re fi rin de ilu ti won tedo si? ( How many days did it take Oduduwa and his followers to reach the place where they settled?)
    Aadota ojo
    Aadorin ojo
    Aadosan ojo
    Aadorun-un ojo
    45s

Teachers give this quiz to your class