placeholder image to represent content

YEAR 6 TEST 2

Quiz by Akin Ajayi

Our brand new solo games combine with your quiz, on the same screen

Correct quiz answers unlock more play!

New Quizalize solo game modes
25 questions
Show answers
  • Q1
    1. Iye Ami ohun ti o wa ni Ede Yoruba ni ______________ (How many tone-marks are in Yoruba Language?)
    merin
    meta
    marun-un
    meji
    30s
  • Q2
    2. Awon konsonanti aramupe to maa n gba Ami ohun Ede Yoruba ni _______ (The nasalized consonants that can take the Yoruba tone marks are?)
    m ati n
    b ati d
    g ati gb
    sh ati s
    30s
  • Q3
    3. Ami ohun ti a ki i ko sile lori leta ni ________ (Which of the tone marks is silent on a letter?)
    Ami oke
    Ami isale
    Ami iwaju
    Ami aarin
    30s
  • Q4
    4. Gbogbo leta wonyi lo maa a gba Ami ohun yato si ___________ (The following letter can receive the Yoruba tone marks except _____)
    on
    un
    am
    en
    30s
  • Q5
    5. Iye ______________ ori oro Yoruba ni iye Ami ohun ori oro naa. (The number of _________ in a word is determine the number of tone mark on the word)
    alifabeeti
    silebu
    konsonanti
    faweli
    30s
  • Q6
    6. Fi Ami ihun si oro yii. "baba" (Put the tone mark on the word "baba")
    do/mi
    mi/re
    re/do
    do/do
    30s
  • Q7
    7. Fi ami si ori "Yoruba"
    re/mi/do
    re/do/mi
    do/re/mi
    mi/do/re
    30s
  • Q8
    8. Fi Ami ohun si ori "omi"
    do/do
    re/re
    mi/mi
    do/mi
    30s
  • Q9
    9. Osu _______________ lo wa ninu odun.
    mookanla
    mewaa
    meejila
    metala
    30s
  • Q10
    10. Ojo ____________ lo wa ninu ose.
    meje
    mejo
    mefa
    marun-un
    30s
  • Q11
    11. Inu osu ti a wa ni ede Yoruba ni __________ (Which month are we in?)
    Agemo
    Ebibi
    Erena
    Ogun
    45s
  • Q12
    12. Osu to koja lo ni ______________ (The last month was?)
    Sere
    Owewe
    Ebibi
    Igbe
    45s
  • Q13
    13. Osu ti o gbeyin odun ni ____________ (The last month of the year)
    Ope
    Belu
    Owara
    Sere
    45s
  • Q14
    14. Ki ni oruko oye Oba Osogbo? (What is the title of the King of Osogbo?)
    Awujale
    Olubadan
    Ataoja
    Osolo
    45s
  • Q15
    15. ki ni oye Oba ilu Ibadan? (What is the title of king in Ibadan?)
    Eleeko
    Akile
    Ataoja
    Olubadan
    45s

Teachers give this quiz to your class